Baba wa ti mbẹ li ọrun.
Ki a bọwọ fun orukọ rẹ.
Ki ijọba rẹ de.
Ifẹ tirẹ ni ki așe li aiye
Bi wọn ti nșe li ọrun
Fun wa ni onjẹ ojọ wa loni
Dari ẹșẹ wa ji wa
Bi ati ndari ẹșẹ ji awọn
Ti oșẹ wa.Mafa wa sinu
Idanwo. șugbon gba wa lọwọ bilisi
Amin
Yoruba