Mo kiọ Mariya
o kun fun oore ọfẹ
Oluwa nbẹ pẹ lu rẹ
Alabukun fun ni iwọ ninun awon obirin
Alabukun fun si ni eso inun rẹ Jesu.
Mariya mimon iya ọlọrun
gba adura fun
A Wa otoși ẹlẹșẹ ni sin sin
ati ni akoko iku awa.
Amin.
Yoruba
Mo kiọ Mariya
o kun fun oore ọfẹ
Oluwa nbẹ pẹ lu rẹ
Alabukun fun ni iwọ ninun awon obirin
Alabukun fun si ni eso inun rẹ Jesu.
Mariya mimon iya ọlọrun
gba adura fun
A Wa otoși ẹlẹșẹ ni sin sin
ati ni akoko iku awa.
Amin.